Jóṣúà 10:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n gba ìlú náà, wọ́n sìti idà bọ̀ ọ́, pẹ̀lú ọba rẹ̀, gbogbo ìletò wọn àti gbogbo ènìyàn ibẹ̀. Wọn kò dá ẹnìkan sí. Gẹ́gẹ́ bí ti Égílónì, wọ́n run un pátapáta àti gbogbo ènìyàn inú rẹ̀.

Jóṣúà 10

Jóṣúà 10:28-43