Jóṣúà 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣúà sì sọ fún wọn pé, “Ẹ má ṣe bẹ̀rù, ẹ má sì ṣe fòyà. Ẹ ṣe gírí, kí ẹ sì mú àyà le. Báyìí ni Olúwa yóò ṣe sí gbogbo àwọn ọ̀ta yín, tí ẹ̀yin yóò bá jà.”

Jóṣúà 10

Jóṣúà 10:22-27