Jóṣúà 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósúà sì wí pe, “Ẹ ṣi ẹnu ihò náà, kí ẹ sì mú àwọn ọba máràrùn jáde wá fún mi.”

Jóṣúà 10

Jóṣúà 10:17-28