Jóṣúà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mósè ìránṣẹ́ ẹ̀ mi ti kú. Nísinsìn yìí, ìwọ àti gbogbo àwọn ènìyàn wọ̀nyí; ẹ múra láti kọjá odò Jọ́dánì lọ sí ilẹ̀ tí Èmi ó fi fún wọn fún àwọn ará Ísírẹ́lì.

Jóṣúà 1

Jóṣúà 1:1-9