Jóṣúà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí àwa ti gbọ́ran sí Móṣè nínú ohun gbogbo, bẹ́ẹ̀ ni àwa yóò máa gbọ́ tìrẹ. Kí Olúwa Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lúù rẹ, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà pẹ̀lú u Móṣè.

Jóṣúà 1

Jóṣúà 1:11-18