Jóṣúà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Rántí àṣẹ tí Móṣè ìránṣẹ́ Olúwa pa fún yín: ‘Olúwa Ọlọ́run yín á fún yin ní ìsinmi, òun yóò sì fún un yín ní ilẹ̀ yìí.’

Jóṣúà 1

Jóṣúà 1:10-18