Jóòbù 9:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí èmi bá wí pé, ‘Èmi ó gbàgbé arò ìbìnújẹ́ mi,èmi ó fi ọkàn lélẹ̀, èmi ó sì rẹ ara mi lẹ́kún.’

Jóòbù 9

Jóòbù 9:21-30