Jóòbù 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tilẹ̀ ṣe pé mo ṣe aláìlẹ́bi,èmi kò gbọdọ̀ dá a lóhùn,ṣùgbọ́n èmi ó gbàdúrà fún àánú.

Jóòbù 9

Jóòbù 9:5-20