Jóòbù 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ yóò ti máa sọ nǹkán wọ̀nyí pẹ́ tó?Tí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ yóò sì máa bí ẹ̀fúùfú ńlá?

Jóòbù 8

Jóòbù 8:1-9