Jóòbù 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni a mú mi ní ìbànújẹ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù,òru ìdáni-lágara ni a sì là sílẹ̀ fún mi.

Jóòbù 7

Jóòbù 7:1-7