Jóòbù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Áà! à bá lè wọ̀n ìbìnújẹ́ mi nínú òṣùwọ̀n,kí a sì le gbé ọ̀fọ̀ mi lé orí òṣùwọ̀n ṣọ̀kan pọ̀!

Jóòbù 6

Jóòbù 6:1-6