Jóòbù 5:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nitorí pé ìwọ ó bá òkúta ìgbẹ́ múlẹ̀,àwọn ẹranko ìgbẹ́ yóò wà pẹ̀lú rẹ ní àlàáfíà.

Jóòbù 5

Jóòbù 5:17-27