Jóòbù 42:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi mọ̀ pé, ìwọ lè e ṣe ohungbogbo, àti pé, kò si ìro inú tí a lè fa sẹ́yìn kurò lọ́dọ̀ rẹ.

Jóòbù 42

Jóòbù 42:1-9