Jóòbù 41:27-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Ó ká ìrin sí bi koríko gbígbẹ àtiidẹ si bi igi híhù.

28. Ọfà kò lè mú un sá; òkútakànnakánná lọ́dọ̀ rẹ̀ dàbí àkékù koríko.

29. Ó ka ẹṣin sí bí àkékù idi koríko;ó rẹ́rin-ín sí mímì ọ̀kọ̀.

Jóòbù 41