Jóòbù 41:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Láti imu rẹ ni èéfín ti jáde wá,bí ẹni pé láti inú ìkòkò tí a fẹ́ iná ìféfé lábẹ́ rẹ̀.

21. Èémi rẹ̀ tinábọ ẹ̀yin, ọ̀wọ́ iná sìti ẹnu rẹ̀ jáde.

22. Ní ọrún rẹ̀ ní agbára kù sí, àtiìbànújẹ́ àyà sì padà di ayọ̀ níwájú rẹ̀.

Jóòbù 41