Jóòbù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áńbọ̀ńtórí àwọn tí ń gbé inú ilé amọ̀,ẹni tí ìbílẹ̀ wọ́n jẹ́ sí erùpẹ̀tí yóò di rírun kòkòrò.

Jóòbù 4

Jóòbù 4:16-21