Jóòbù 39:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi ẹsẹ̀ halẹ̀ nínú àfonífojì, ó sì yọ̀ síagbára rẹ̀; ó lọ jáde láti pàdé àwọn ìhámọ́ra ogun.

Jóòbù 39

Jóòbù 39:18-25