Jóòbù 39:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Ìwọ ó gbẹ́kẹ̀ lée nítorí agbára rẹ̀pọ̀ ìwọ ó sì fi iṣẹ́ rẹ lé e lọ́wọ́?

12. Ìwọ le gbẹ́kẹ̀ le pé, yóò mú èsooko rẹ̀ wá sílé, àti pé yóò sì kó ọ jọ sínu àká rẹ?

13. “Ìyẹ́ abo ògòǹgò ń fi ayọ̀ fì;Ṣùgbọ́n a kò le fi àká we ara wọn ní ìyẹ́ àti ìhùhù

Jóòbù 39