Jóòbù 37:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn mọ̀nàmọ́ná Òun kan fọ̀ramúramù; ó sì fi ohùn ọláńlárẹ̀ sán àrá; òhun kì yóò sì dáàrá dúró nígbà tí ó bá ń gbọ́ ohùn rẹ̀.

Jóòbù 37

Jóòbù 37:1-5