Jóòbù 35:15-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Ṣùgbọ́n nísinsìnyí nítorí tí ìbínúrẹ̀ kò tí ṣẹ́ ọ níṣẹ̀ẹ́, òun kò ha lèhun ímọ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwà búrubú bí?

16. Nítorí náà ní Jóòbù se ya ẹnu rẹ̀lásán ó ṣọ ọ̀rọ̀ di púpọ̀ láìsí ìmọ̀.”

Jóòbù 35