Jóòbù 34:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Íṣe bí ti inú rẹ̀ pe òun ó san ẹ̀ṣẹ̀ padà?Ǹjẹ́ òun yóò san án padà bíìwọ bá kọ̀ ọ́ láti jẹ́wọ́ tàbíìwọ ìbá fẹ́ kì í ṣe èmi; Pẹ̀lúpẹ̀lú ohun tí ìwọ mọ̀, sọ ọ!

Jóòbù 34

Jóòbù 34:27-35