Jóòbù 34:28-32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. kí wọn kí ó sì mú igbe ẹkúnàwọn tálákà lọ dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, òunsì gbọ́ igbe ẹkún aláìní

29. ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá dákẹ́ síbẹ̀, ta ni yóò dá lẹ́bi? Nígbà tí ó bápa ojú rẹ̀ mọ́, ta ni yóò lè rí i?Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe é orilẹ̀ èdè tàbi sí ènìyàn kan ṣoṣo;

30. Kí àgàbàgebè kí ó má báà jọbakí wọn kí ó má di ìdẹ̀wò fún ènìyàn.

31. “Nítorí pé ẹnìkan ha lè wí fúnỌlọ́run pé, èmi jẹ̀bí; èmi kò sì ní ṣẹ̀ mọ́?

32. Èyí tí èmi kò rí ìwọ fi kọ́ mi bimo bá sì dẹ́sẹ̀ èmi kì yóò ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́.

Jóòbù 34