Jóòbù 34:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ibi òkùnkùn, tàbí ojìjìikú, níbi tí àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ yóò gbé sá pamọ́ sí.

Jóòbù 34

Jóòbù 34:18-26