Jóòbù 33:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jási ìdúró ṣinṣinọkàn mi, ètè mi yóò sì sọ ìmọ̀ mi jáde dájúdájú.

Jóòbù 33

Jóòbù 33:1-10