Jóòbù 33:19-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. A sì nà á lórí ibùsùn ìrọra rẹ̀;Pẹ̀lúpẹ̀lú a fi ìjà egungun rẹ̀ ti ó dúró pẹ́ nà án.

20. Bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mírẹ kọ ounjẹ, ọkàn rẹ̀ sì kọ oúnjẹ dídùn.

21. Ẹran ara rẹ̀ run, títí a kò sì fi lè ríi mọ́egungun rẹ̀ tí a kò rí sì ta jáde.

22. Àní ọkàn rẹ̀ sì súnmọ́ ìsà òkú,ẹ̀mí rẹ̀ sìsúnmọ́ ọ̀dọ̀ àwọn ìranṣẹ́ ikú.

Jóòbù 33