Jóòbù 32:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí dákẹ́ láti dá Jóòbù lóhùn, nítorí ó ṣe olódodo lójú ara rẹ̀.

Jóòbù 32

Jóòbù 32:1-4