Jóòbù 31:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ènìyàn ni mo ha bẹ̀rù bí?Tàbí ẹ̀gan àwọn ìdílé ní ń bà mí ní ẹ̀rù?Tí mo fi p'ẹnu mọ́, tí èmí kò sì fi jáde sóde?

Jóòbù 31

Jóòbù 31:25-40