Jóòbù 31:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ó bá ṣepé mo yọ̀ sì ìparun ẹnití ó korìíra mi. Tàbí bí mo bá sì gbéra sókè, nígbà tí ibi bá a.

Jóòbù 31

Jóòbù 31:27-36