Jóòbù 31:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ó bá ṣe pé mo fi wúrà ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé mi,tàbí tí mo bá wí fún fàdákà dídára pé, ‘Ìwọ ni ààbò mi;’

Jóòbù 31

Jóòbù 31:18-25