Jóòbù 31:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo bá sì gbé ọwọ́ mi sókè síaláìní baba, nítorí pé mo rí ìrànlọ́wọ́ mi ní ẹnu ibodè,

Jóòbù 31

Jóòbù 31:18-31