Jóòbù 31:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ni èmi ó ha ṣe nígbà tí Ọlọ́runbá dìde? Nígbà tí ó bá sì ṣe ìbẹ̀wò, ohùn kí ni èmi ó dá?

Jóòbù 31

Jóòbù 31:10-15