Jóòbù 30:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ó ti wù kí ó rí, ẹnìkan kí yóòha na ọwọ́ rẹ̀ nígbà ìṣubu rẹ̀, tàbí kì yóò ké nínú ìparun rẹ̀.

Jóòbù 30

Jóòbù 30:17-27