Jóòbù 30:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ gbémi sókè sí inú ẹ̀fúùfù,ìwọ múmi fò lọ, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ sì sọ mí di asán pátapáta.

Jóòbù 30

Jóòbù 30:14-24