Jóòbù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí òkùnkùn àti òjìjì ikú fi ṣe ti ara wọn;kí àwọ-sánmọ̀ kí ó bà lé e;kí ìṣúdúdú ọjọ́ kí ó pa láyà.

Jóòbù 3

Jóòbù 3:1-14