Jóòbù 28:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkùta tópásì ti Kúsì kò tóẹgbẹ́ rẹ̀; bẹ́ẹ̀ ni a kò le fi wúrà dáradára díwọ̀n iye rẹ̀.

Jóòbù 28

Jóòbù 28:15-25