Jóòbù 27:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Ètè mi kì yóò sọ̀rọ̀ èké, Bẹ́ẹ̀ niahọ́n mi kì yóò sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.

5. Kí a má ríi pé èmi ń dá yín láre;títí èmi ó fi kú, èmi kì yóò sí ìwà òtítọ́ mi kúrò lọ́dọ̀ mi.

6. Òdodo mi ni èmi dìmú ṣinṣin,èmi kì yóò sì jọ̀wọ́ rẹ̀ lọ́wọ́; àyàmi kì yóò sì gan ọjọ́ kan nínú ọjọ́ ayé mi.

7. “Kí ọ̀ta mi kí ó dàbí ènìyànbúburú, àti ẹni tí ń dìde sími kí ó dàbí ẹni aláìsòdodo.

Jóòbù 27