Jóòbù 24:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Kíyèsí i, bí i kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ìgbẹ́ nínú ijùni àwọn talákà ijáde lọ sí iṣẹ́wọn; Wọ́n a tètè dìde láti wáohun ọdẹ; ijù pèsè oúnjẹ fúnwọn àti fún àwọn ọmọ wọn

6. Olúkulùkù a sì ṣa ọkà oúnjẹ ẹranrẹ̀ nínú oko, wọn a sì ká ọgbà àjàrà ènìyàn búburú.

7. Ní hòòhò ni wọn má a sùn láìní aṣọ,tí wọn kò ní ìbora nínú òtútù.

Jóòbù 24