Jóòbù 24:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn ni ó wà nínú àwọn tí ó kọ̀ìmọ́lẹ̀; Wọn kò mọ̀ ipa ọ̀nà rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò dúró nípa ọ̀nà rẹ̀.

Jóòbù 24

Jóòbù 24:7-15