Jóòbù 23:16-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Nítorí pé Ọlọ́run ti pá mi ní àyà,Olodùmáarè sì ń dààmú mi,

17. Nítorí tí a kò tí ì ké mi kúròníwájú òkùnkùn, bẹ́ẹ̀ ni kò paòkùnkùn biribiri mọ́ kúrò níwájú mi.

Jóòbù 23