Jóòbù 23:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ni Jóòbù sì dáhùn wí pé:

2. “Àní lónìí ni ọ̀ràn mi korò; ọwọ́mí sì wúwo sí ìkérora mi.

3. Áà! èmi ìbá mọ ibi tí èmí ìbá wáỌlọ́run rí, kí èmí kí ó tọ̀ ọ́ lọ sí ibùgbé rẹ̀!

4. Èmi ibá sì to ọ̀ràn náà níwájú rẹ̀,ẹnu mi ìbá sì kún fún àròyé.

Jóòbù 23