Jóòbù 20:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbísí ilé rẹ̀ yóò kọjá lọ, àti ohunìní rẹ̀ yóò ṣàn dànù lọ ni ọjọ́ ìbínú Ọlọ́run.

Jóòbù 20

Jóòbù 20:23-29