Jóòbù 20:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ìwà búburú tilẹ̀ dún ní ẹnurẹ̀, bí ó tilẹ̀ pa á mọ́ nísàlẹ̀ ahọ́n rẹ̀,

Jóòbù 20

Jóòbù 20:2-21