Jóòbù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Sàtánì jáde lọ kúrò níwájú Olúwa, ó sì sọ Jóòbù ní oówo kíkan kíkan láti àtẹ́lẹṣẹ̀ títí dé àtàrí rẹ̀

Jóòbù 2

Jóòbù 2:1-8