Jóòbù 19:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọgbà dí ọ̀nà mi tí èmi kò le èkọjá, Ó sì mú òkùnkùn ṣú sí ipa ọ̀nà mi.

Jóòbù 19

Jóòbù 19:1-17