Jóòbù 19:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí èmi ó rí fún ara mi, tí ojúmi ó sì wo, kì sì íṣe tiẹlòmìíràn; ọkàn mi sì dákú ní inú mi.

Jóòbù 19

Jóòbù 19:25-29