Jóòbù 19:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará inú ilé mi àti àwọnìránṣẹ́bìnrin mi kà mí sí àjèjì;èmi jásí àjèjì ènìyàn ní ojú wọn.

Jóòbù 19

Jóòbù 19:11-22