Jóòbù 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìrìn ẹṣẹ̀ agbára rẹ̀ yóò di fífọn;ìmọ́lẹ̀ òun tìkárarẹ̀ ni yóò bí i ṣubú.

Jóòbù 18

Jóòbù 18:1-14