Jóòbù 17:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọlọ́run ti sọ mi di ẹni òwe fúnàwọn ènìyàn; níwájú wọn ni mo dàbí ẹni ìtutọ́ sí ní ojú.

Jóòbù 17

Jóòbù 17:2-14