Jóòbù 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti jókòó jẹ́ẹ́, ṣùgbọ́n ó fà mí já;ó sì dì mí ọrùn mú, ó sì gbọ̀nmí túútúú, ó sì gbé mi kalẹ̀ ṣe àmì—ìtàfàsí rẹ̀.

Jóòbù 16

Jóòbù 16:3-13