Jóòbù 15:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì gbọ̀n àìpọ́n èṣo rẹ̀ dànù bí i àjàrà,yóò sì rẹ̀ ìyanna rẹ̀ nù bí i ti igi Ólífì.

Jóòbù 15

Jóòbù 15:31-35